Òṣùwọ̀n fún dídá Ọ̀rọ̀-Ìṣe mọ̀nínú Èdè Yorùbá

Authors

  • Oyè Táíwò Yunifásítì Ìbàdàn, Ìbàdàn

Keywords:

ọ̀rọ̀-ìṣe èdè Yorùbá, ìtumọ, ìlò, ìhun, ẹ̀hun
         Abtract Views | PDF Download: 67 / 95

Abstract

Yoruba 

Ọ̀rọ̀-ìṣe ṣe pàtàkì nínú ẹ̀hun, àwọn onímọ̀ èdè Yorùbá sì tí fi oríṣiríṣi ẹ̀yà ọ̀rọ̀-ìṣe èdè Yorùbá hàn. Àmọ́ kò sí òṣùwọ̀n tí ó fojú hàn tía lè sọ pé àwọn onímọ̀ ṣàmúlò láti ṣàtúnpín ọ̀rọ̀-ìṣe èdè Yorùbá. Nínú bébà yìí, mo ṣàmúlò òṣùwọ̀n mẹ́rin láti pín àwọn ọ̀rọ̀-ìṣe èdè Yorùbá sí ìsọ̀rí. Awọn òṣùwọ̀n náàni ìtumọ̀ , ìlò, ìhun àti ìrísí, àti ìṣesí nínú ẹ̀hun. Àwọn ọ̀rọ̀-ìṣe tí mo sì yà sọ́ tọ̀ ni ìwọ̀nyí: asọ̀ṣẹ̀lẹ̀ , ajúwe, asọ̀rírí, aṣèròyìn, apàṣẹ tàbí aṣẹ̀bẹ̀ , aṣèbéèrè, aṣàpèpadà, abọ́dé, alákànpọ̀ , ayolùwà (a-yan-olùwà),ayànbọ̀ (a-yan-àbọ̀), asolùwàdàbọ̀ (a-sọ-olùwà-di-àbọ̀), agbàbọ̀ , aláìgbàbọ̀, agbàmúpé, ẹlẹ́ là, àsínpọ àti abá wúnrẹ̀n aláìnítumọ̀ àdámọ́ rìn. Mo pín ọ̀rọ̀-ìṣe alákànpọ̀ sí márùn-ún: ò̩ rò̩ -ìs̩ e abọ́dé àti àpólàorúkọ/ò̩ rò̩ -orúkọ, ò̩ rò̩ -ìs̩ e abọ́dé, ò̩ rò̩ -orúkọ àti ò̩ rò̩ -atọ́kùn/àpólà atọ́kùn, ò̩ rò̩ -ìs̩ e abọ́dé àti àpólàató̩ kùn aṣàmúpé, ò̩ rò̩ -ìs̩ e abọ́dé méjì tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ,àti ò̩ rò̩ -ìs̩ e ẹlẹ́ là pẹ̀ lú àbọ̀ . Ẹ̀yà ọ̀rọ̀-ìṣeàsínpọ̀ mẹ́rinni mo yà sọ́tọ̀ , mo sì ṣàlàyé ìdí tí a kò fi lè gba ọ̀rọ̀-ìṣe àsínpọ̀ aṣàpọ́nlé àti ọ̀rọ̀-ìṣe àsínpọ̀ oníbọ̀ gẹ́gẹbí ẹ̀yà ọ̀rọ̀-ìṣeàsínpọ̀ ní èdè Yorùbá.

English

The verb is an obligatory part of the verb phrase. In the Yorùbá language, scholars have given various types of the Yorùbá verbs. However, these scholars did not spelt out the yardstick or criteria used in the identification of these verbs. In the paper, I empolyed four criteria to identify Yorùbá verbs in different constructions. These are meaning, use, structure or form and behavioural patterns in constuctions. With these four criteria, I identified eighteen (18) different types of verbs in Yorùbá. These are action verbs, descriptive verbs, experiential verbs, report verbs, imperative verbs, interogative verbs and echo verbs. Others are simple verbs, compound verbs, subject selecting verbs, object selecting verbs, symmetrical verbs, transitive verbs and intransitive verbs. The remaining verb types identified in this paper are complement selecting verbs, serial verbs, splitting verbs and functors or particle selecting verbs. Serial verbs are further subdivided into durational, consequential, causative and sequential serial verbs

Author Biography

Oyè Táíwò, Yunifásítì Ìbàdàn, Ìbàdàn

 

 

 

References

Afọlayan, A. (1982) (ed) Yorùbá Language and Literature, Ìbàdàn: UPL and Unife Press.

Awóbùlúyì, O. (1967). Studies in the Syntax of the Standard Yorùbá Verb, Ph.D Thesis, Colombia University, USA.

Awóbùlúyì, O. (1972). “On the Classification of Yorùbá Verb”, in Bámgbóṣé (ed.) pp. 119-134.

Awóbùlúyì, O̩ . 1978. Essentials of Yorùbá Grammar, Ìbàdàn: UPL.

Awóbùlúyì, O. (1982). “The Yorùbá Verb Phrase”, in Afọlayan, A. (ed) pp. 225-246.

Awobuluyi, O̩ . 2013. Ẹ̀kọ Gírámà Èdè Yorùbá. Oṣogbo, ATAM Limited

Bámgbóṣé, A. (1966). A Grammar of Yorùbá, Cambridge: CUP.

Bámgbóṣé, A. (1967). A Short Yorùbá Grammar, Ìbàdàn: HEB.

Bámgbóṣé, A. (1972a). “Introduction”, in Bámgbóṣé (ed.) pp 1 - 17

Bámgbóṣé, A. (1972b). “What is a Verb in Yorùbá”, in Bámgbóṣé (ed.) pp 17-60.

Bámgbóṣé, A. (1972c). (ed.) The Yorùbá Verb Phrase, Ìbàdàn: UPL.

Bámgbós̩ é, A. 1990. Fonó̩ ló̩ jì àti Gírámà Yorùbá. Ìbàdàn: UPL.

Oyelaran, O O. (1982). “On the Scope of Serial Verb Constructions’, Studies in African Linguistics, Vol. 13. No. 2.

Taiwo, O. 2011. Mofọ lọ jì: Àtúnṣe kejì: Ibadan, Akada Universal Books

Taiwo, O. 2014a. “The morpho-syntactic interaction and the derivation of nominal compounds in Yorùbá’’ International Journal of Language Studies Vol. 8 No 1 o.i. 67- 92

Taiwo, O 2014b. Ìsọ̀rí Ọ̀rọ̀ Èdè Yorùbá I: Ibadan, DLC, UI

Taiwo, O àti O̩ lakolu, T. 2010. “Ò̩ rò̩ - ìs̩ e Alákànpò̩ ní Èdè Yorùbá’’ Research in African Languages and Linguistics (RALL) Vol. 10 o.i. 90-112

Taiwo, O. (Ó ń bò̩ ló̩ nà). Gírámà.

Yusuff, O̩ . 1995. Gírámà Yorùbá Àkò̩ tun: Ní Ìlànà Ìs̩ ípayà Onídàrọ, Ijebu-ode: S̩ ebiotimo̩ Publications.

Downloads

Published

2018-03-01

How to Cite

Táíwò, O. . (2018). Òṣùwọ̀n fún dídá Ọ̀rọ̀-Ìṣe mọ̀nínú Èdè Yorùbá. Journal of The Linguistic Association of Nigeria, 21(1), 76–96. Retrieved from https://jolan.com.ng/index.php/home/article/view/138

Most read articles by the same author(s)

1 2 > >>