Yoruba: Ìpàṣamo ̣̀O ̣̀ro ̣̀nínú Àwọn Ìpolongo Ìbò Ẹgbe ̣́Òṣèlú Àko ̣́o ̣̀dù lórí Rédíò ní Ìpínle ̣̀O ̣̀yo ̣́<br> English: The Use of Allegory in the Political Jingles of Accord Party on Radio in Oyo State

Authors

  • Deborah Ọmọlará ÌLO ̣̀RI Department of Linguistics and African Languages

Keywords:

verbal means, tyranny, campaign, political jingles, allegory, olùdíje, ìbò, ìpolongo, ìṣàkóso, ẹgbẹ́ òṣèlú, àṣamo
         Abtract Views | PDF Download: 74 / 45

Abstract

Yorùbá

Yorùbá bọ̀wọ́n ní òwe lẹṣin ọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀lẹsin òwe, bí ọ̀rọ̀bá sọnù, òwe la fi ń wá a. Bẹ́ẹ̀gẹ́ gẹ́ni àṣamọ̀jẹ́láàárín àwọn ọmọ Yorùbá. Ìpàsamọ̣̀ jẹ̣́ ọ̣̀nà tí ènìyàn ń gbà fi ẹ̣̀hónú rẹ̣̀ hàn láìmú ìjà tàbí ogun lọ̣́wọ̣́ . Nítorí pé ní ọ̀polọpọ̀ìgbà ni àwọn Yorùbá máa ń fẹ́fi èrò inú wọn hàn, èyí tí ó le jẹ́ayọ̀, ìbínú, ìbànújẹ́tàbí èyí tí ó fi ìlòdìsí hàn. Orísìírísìí ọ̀nà ni wọ́n sì fi le fi èyí hàn, pàápàá jùlọ nígbà tí ẹni tí wọ́n fẹ́fièrò yìí hàn fún bá jẹ́alágbára tàbí ẹni ńlá tí kò ṣe é dojú kọ tààrà. Nínú iṣẹ́ìwádìí yìí, a wo bí ẹgbẹ́òṣèlú Àkọ́ọ̀dù ní ìpínlẹ̀Ọ̀yọ́ṣe fi ọ̀rọ̀pàṣamọ̀nínú àwọn ìpolongo ìbò wọn nínú ètò ìbò ọdún 2015 tíó kojá. A ṣe àkíyèsí pé wọ́n fi àṣamọ̀frere ẹgbẹ̣́ wọn pẹ̣̀ lú kùdìẹ̀kudiẹ ẹgbẹ̣́ alatakò wọn hàn. Ẹgbẹ́òṣèlú Àkọ́ọ̀dù fi àṣamọ̀fi kùdìẹ̀kudiẹ ìsàkóso ìjọba tí ó wà lóde hàn, wọ́n sì fọnrere olùdíje fún ipògómìnà láti inú ẹgbẹ́wọn gẹ́ gẹ́bí ẹni tí ó le ṣe é láì kù síbì kan. A sì tún ṣàkíyèsí pé àgbékalẹ̀wọnnínúìpolongo ìbò yìí mú kí ìpolongo wọn lọ́ọ́ rìn tí ó sì kún fún àwọn èdè tí ó wuyì. A sì tún gbìyànjúláti yẹ ìtumọ̀àwọn àṣamọ̀yìí wò àti ìlò wọn. Gbogbo àgbéyẹ̀wò wa yìí ni a gbé lé orí tíọ́rì adálóríìtumọ̀. Iṣẹ̣́ ìwádìí fẹ̣́ṣe àfihàn ìdí gan an tí ẹgbẹ́ òṣèlú Àkọ́ọ̀dù ní ìpínlẹ̀Ọ̀yọ́ṣe lo àṣamọ̀nínú àwọnìpolongo ìbò wọn nínú ètò ìbò ọdún 2015 tí ó kojá tí wọn kò fi ṣe àmúlò ọ̣̀nà ìbánisọ̣̀rọ̣̀ míràn yàtọ̣̀sí àṣamọ̣̀ . A ó tún yànnàná ìtumọ̣̀ àwọn ọ̣̀rọ̣̀ ìperí wọ̣́n lò àti ìdí tí wọ̣́n fi lo irú àwọn ọ̣̀rọ̣̀ bẹ̣́ẹ̣̀.

English

Allegory is a symbolic representation which can be interpreted to reveal a hidden meaning, usually a moral or political one. It is a phenomenon commonly used among Yoruba to avoid war, open confrontation or uproar. It can be done through various means like use of song, drum or verbal means. Yoruba people express their displeasure about somebody through various means especially when the person concern is powerful or influential which makes him unapproachable. It is this approach that Accord party made use to ridicule the ruling governor and his party, and praised as well as publicized their candidate as the only person that can rescue the people of Oyo state from the tyranny rule of the ruling governor. This made their campaign as well as manifesto weighty and convincing. This work examines the choice of words used, means and meaning of the words used through lexical semantic theory. The data used were collected from the political jingles of the Accord party of 2015. This work reveals the reason behind the use of this approach that Accord party made use to ridicule the ruling governor and his party and as well examines their choice of words used and connotative meaning of each words used.

Author Biography

Deborah Ọmọlará ÌLO ̣̀RI, Department of Linguistics and African Languages

University of Ibadan, Ibadan

 

References

Akinadé A.M. (2016) A Sociolinguistic Analysis of Verbal word-Fare in Political Jingles in Ọyọ State unpublished B.A. project. University of Ibadan.

Akinwùmí Ìṣọ̣̀lá (2010) Ẹnà: Code – Talking in Yorùbá. Journal of West African Language XII,1 1982 pp 130 – 140

Austin, J.L.(1962) How to do Things with Words; Clarendon Press.

Carnap, R. (1956) Meaning and Necessity; University of Chicago Press.

John L. Saeed (2003) Semantics, Second Edition. Blackwell’ Arówóṣẹgbẹ̣́, M. (2015) Lítíréṣọ̣̀ Àti Àṣà Yorùbá. Heavensway Publishers. Ibadan.

Olú D. Àti A. Jẹ̣́jẹ̣́(1975) Àwọn Àṣà àti Òrìṣà Ilẹ̣̀ Yorùbá; Oníbọn-Òjé Press &Book Industries (Nig) Ltd.

Ọlawuyi, M. A, Ọ. (2011) Àkójọpọ̣̀ ẹ̣̀ẹ̣́dẹ̣́gbaàje òwe àti Àsàyàn ọ̣̀rọ̣̀ Yorùbá. Multiple Dee Nigeria Limited.

Palmer, F.R (1981) Semantics, Second edition. Cambridge: Cambridge University Press.

Ruth M. Kempson (1977) Semantic Theory. Cambridge: Cambridge University Press. Radio Jingle of Accord Party Ọyọ State (2015)

Downloads

Published

2018-12-01

How to Cite

Ọmọlará ÌLO ̣̀RI D. . (2018). Yoruba: Ìpàṣamo ̣̀O ̣̀ro ̣̀nínú Àwọn Ìpolongo Ìbò Ẹgbe ̣́Òṣèlú Àko ̣́o ̣̀dù lórí Rédíò ní Ìpínle ̣̀O ̣̀yo ̣́<br> English: The Use of Allegory in the Political Jingles of Accord Party on Radio in Oyo State . Journal of The Linguistic Association of Nigeria, 21(3), 214–220. Retrieved from https://jolan.com.ng/index.php/home/article/view/191