@article{Idayat Oyèníkee_2018, title={Àbùdá Ìmédélò nínú Ìpèdè Apanile ̩́rìn-ín lórí O nà ìbániso ro to ̩́ro ̩́-fo ̩́n-kálé}, volume={21}, url={https://jolan.com.ng/index.php/home/article/view/159}, abstractNote={
Yoruba

È̩rín jé̩ò̩na kan pàtàkí tí è̩dá máa ń gbà fi ìmò̩sílára hàn lóri ìse tàbí ìpèdè ajemáwàdà. Onírúurú àwononímoló ti siselórí ìpèdè apanilerìn- ín, ní pàtàkí jù lonínú àwon ìwé lítíréso Yorùbá. Lárawo n latirí Adejumo(2008), Àlàbá (2008), Àrè̩mú (2005), Faké̩ye(2016), Oaté̩jú (2008) àti Ìsò̩lá (2008) àti Raji (2010). Púpò̩nínú àwon is é̩wò̩nyí ló dá lórí àkójopò̩orísun ìpèdè apanilé̩rín –ín, ò̩nà ìfini-sè̩fè̩,àǹfàání àtí ìwúlò àwàdà, èfè̩sís àti àpárá dídá bí ò̩nà ìbánisò̩rò̩láwùjo àmò̩tí oó̩jà ìwádìí kò tí tàndé ìrúfé̩ìpèdè apanilé̩rín- ín tí a máa ń kà lórí ìtàkùn-àgbáyé. Látàrí èyí, isé̩ìwádìí yìí se àgbéyè̩wó àtiìtúpalè̩ipa tí àwon àbúdà ìmédèlò (pragmatic features) kó nínú ìtúmò̩ìpèdè apanlé̩rìn-ín ti orí ò̩nàìbánisò̩rò̩tó̩ró̩-fó̩n-kálé. Orí tíó̩rí àìbárámu (incongruity theory) ni a gbé ìtúpalè̩àkójoèdè fáyewò èyítí a sàkójoláti orí è̩roìbánisò̩rò̩tó̩ró̩-fó̩n-kálé ‘whatapp, facebook àti twitter’ kà. Ìwádìí fihàn pé oríìfòròdárà onípó̩nna ní púpò̩àwon ìsoàpanilé̩rín-ín lórí eroìbánisò̩rò̩tó̩ró̩-fó̩n-kálé máa ń tè̩kí won tólè jisé̩tí òlùsò̩rò̩rán wó̩À-mó̩̩̩̀̀ -on- mò̩- ṣè̩ḍ̀ á yàtò̩̣̀sí èyí tí a kò fé̩̣̀kí ó ṣẹlè̩,̣̀ ní ìbámu pè̩lú àwon àbùdáìmédèlò nínú ìbánisò̩rò̩ ojoojumo ni pupowon máa ń jé̩. Tó bé̩è̩, ti wó̩n fi yàtò̩̣̀sí àwon tí a lè yàgò fúnnígbà tí a bá ń sàgbékalè̩ìsotí kò mú è̩rín dání. Ní ìbámu pè̩ḷ̀ú àkóónú ìmò̩ìmédèlò, ìsé̩fìdí remúlè̩pé lórí èrò mò̩-ó̩n nú, ìsekókó-èrò, àti íyapa sí òsùnwò̩n alájosepò̩ti ‘Grice’ ní àwon adé̩rínpòsónú máagbé ìfò̩rò̩dárà onípó̩n-ó̩n-na to jé̩atokùn ìsé̩won kà.

English

Laughter is an emotional process by which people react towards humourous texts. Extant studies on humour such as Adejumo(2008), Àlàbá (2008), Àremú (2005), Faké̩ye(2016), O laté̩ jú (2008) àti Ìsò̩lá(2008) àti Raji (2010) have focused on literary analysis especially on the etymology, taxonomy, approach, and their social impact as a means of communication in the society with little attention paid to the pragmatic analysis of humourous texts on social media. This study is therefore, designed to investigate the impact of pragmatic features in humourous texts on Social media with a view to determining their adherence or otherwise towards the contextual interpretation of the humourous text. The incongruity theory of humour served as the framework. Eight humourous texts were purposively selected from Whatsapp and Facebook. The finding revealed that majority of humourous texts on social media is constructed through punning which contextual necessitates ambiguity. In relation to pragmatic features, syntax of these texts is often and thoughtful structured in contrast with syntax of day-to-day-speeches. This established lexis in humour as being different from those which speakers could flout in non-humourous text. In accordance with the tenet of pragmatics, the study identified presupposition, relevance principle and Grice’s conversational maxims as the pragmatic features through which the speaker cleverly presents the punning and incongruity ideas through which his intended meaning’s implicature provokes laughter.
}, number={2}, journal={Journal of The Linguistic Association of Nigeria}, author={Idayat Oyèníkee Saka,}, year={2018}, month={Sep.}, pages={37–46} }